Coronavirus: Wo ohun tí o ní láti ṣe láti dáàbò bo ara rẹ
Arun Coronavirus ti tan de, o kere tan, ọgọrin orilẹ-ede, ilẹ Gẹẹsi ati Naijira si jẹ ọkan lara rẹ. Ṣugbọn kinni arun yii, ati pe bawo ni o ṣe n tan ka? Ìjọba ń ṣe afárá Eko Bridge l’Eko, àwọn ọ̀nà àbùdá tí ẹ lèè gbà nìyí Coronavirus: Kí ni àwọn àpẹrẹ àrùn náà?
Coronavirus: Àwọn ohun tí a kò tíì mọ̀ nípa àrùn Covid-19
Niṣe ni ọrọ naa jọ bi ẹni pe ati ogun ọdun la ti n ba bọ ṣugbọn ko ju oṣu Kejila ọdun 2019 to kọja ta bẹrẹ si ni jẹ ọrọ Coronavirus lẹnu. Toun ti akitiyan awọn onimọ sayẹnsi jakejado agbaye,diẹ lohun ta mọ nipa arun yi ti gbogbo aye si ti wa n ṣakitiyan lati wa idahun si ibeere to mu wa.
Nítorí ‘ẹbọra Coronavirus,’ Ọọ̀ni Ogunwusi gbé orò jáde ní ilé Ifẹ̀
Gbogbo agbaye ti n damu lori arun yii fun ọpọlọpọlọ oṣu bayii laisi ọna abayọ kan to dan mọran. Arun Coronavirus ti sọ ara rẹ di ẹrujẹjẹ ni gbogbo ilẹkilẹ, ẹbọra ti n se gbogbo aye mọle porogodo. Ṣe awọn agba si bọ wọn ni to ba runi loju, aa bi ilẹ leere.
Coronavirus in Nigeria: Ìpínlẹ̀ Eko bẹ̀rẹ̀ fínfín àyíká nítorí Coronavirus – BBC News Yorùbá
Coronavirus in Nigeria: Ìpínlẹ̀ Eko bẹ̀rẹ̀ fínfín àyíká nítorí Coronavirus Lati asiko ti arun Coronavirus ti di gbajugbaja lorilẹede Naijiria ni ijọba ti n wa oniruuru ọna lati koju rẹ ati lati daabo bo awọn araalu kuro lọwọ rẹ. Ni ipinlẹ Eko, ijsba ipinlẹ naa pẹlu n gbe igbesẹ lati rii pe àwọn eeyan ipinlẹ naa wa ninu alaafia laisi ewu.
Àbáwọlé – BBC News Yorùbá
Ibí yìí lo ti máa rí ojúlówó ìròyìn àjáàbalẹ̀ lórí ojú ọjọ́, ètò ọrọ̀ ajé, ìdánilárayá, òṣèlú, ìròyìn àgbáyé ní ìṣẹ́jú kan àtàwọn míràn. BBC Yorùbá máa ń ṣe ìròyìn àkànṣe, fídíò, ọ̀rọ̀ ẹnu, fọ́tò tó jojú ní gbèsè àti itọ́ni onísọ̀rọ̀-ǹ-gbèsì tó dáńtọ́